Showing posts with label Ìtàn/Story. Show all posts
Showing posts with label Ìtàn/Story. Show all posts

ÌYÀ TÍ MO JẸ NÍ ÌWÓ [A SHORT YORÙBÁ STORY] BY ISRAEL AYANWUYI

ÌYÀ TÍ MO JẸ NÍ ÌWÓ Láti ọwọ́ Israel Ayanwuyi Bí a kò bá r'ẹ́ni fẹ̀yìntì bí ọ̀lẹ làárí.  Ìyá tí mo jẹ ní Ìwó kọjá àfi ẹnu sọ. Ìròyìn kò tó àmójúbà; ti àsọrégèé kọ́, kì í ṣe[....]

Read More

ÀRÒGÚN: ÀWÍJÀRE

ÀRÒGÚN: ÀWÍJÀRELáti ọwọ́ Israel Ayanwuyi  Bí a bá ń sọ̀rọ̀ nípa ọjọ́ iwájú orílẹ̀-èdè kan tàbí ìrètí ọjọ́ ọ̀la tó dára àgbáyé, ọ̀rọ̀ àwọn ọmọdé ló yẹ ká kọ́kọ́ mú gbọ́,[....]

Read More

ÌTÀN: ÌBÀNÚJẸ́ ỌJỌ́ KAN

ÌTÀN: ÌBÀNÚJẸ́ ỌJỌ́ KANLáti ọwọ́ Israel Ayanwuyi Lọ́gán tí mo rí ìmọ́lẹ́ ọjọ́ ajé, mo gbéra nílẹ̀, mo kí Olódùmarè kú òwúrọ̀ nítorí pé Òun náà ni Ọba àjìkí, Òun tún ni Ọba[....]

Read More

About Us

AIF MEDIA is where we tune lives with tongue and culture. AIF MEDIA is a medium with passion to unite Yorùbá people to their heritage; promote and preserve godly virtues from Yorùbá culture, tradition and lifestyle; and give poetic admonitions.

Our Networks:
YorùbáDùnlÉdè | Ìtumọ̀ | Biblicopoetry

Contact Info

Email: ayanwuyiisrael@gmail.com

Phone: +234 7032932463

Address: Àyọkà Road, Round-About Area, Ògbómọ̀ṣọ́, Ọ̀yọ́ State

YouTube: AIF MEDIA

Facebook, Twitter and Instagram: AIF MEDIA