1. Quarantine
Ìsémọ́lé
2. Self-Isolation
Ìdánìkanwà
3. Coronavirus
Kòkòrò àìfojúrí kòrónà
4. Social distancing
Súnfúnmi-kí-n-súnfún-ẹ
5. Hand sanitizer
ohun èlò olómi ìmọ́wọ́mọ́tóní.
6. Mask
Ìbomú-bẹnu
7. Gloves
Ìbọ̀wọ́
8. Ventilator
Ẹ̀rọ Amúnimí / ẹ̀rọ gbẹ́mìíró
9. Pandemic
Àjàkálẹ̀ Ààrùn(kárí àgbáyé)
10. Intensive Care Unit
yàrá ìtọ́jú alákànṣe
11. Fever - Ibà
12. Cough- Ikọ́
13. Sore throat - Ọ̀nà ọ̀fun dídùn
14. Tiredness/fatigue
Ara rírẹ̀
15. Aches
Ara ríro/Ara dídùn
16. High blood pressure
Ẹ̀jẹ̀ ríru
17. Underlying medical condition
Àìlera-abẹ́nú
18. Respiratory disease
Àrùn èémí
19. Lungs
Ẹdọ̀ fóró
20. Trachea/Windpipe
Ọ̀nà èémí ọ̀fun.
Ṣíṣe Ìgbéga Àwọn Ogún Dáradára Yorùbá Ló Jẹ Wá Lógún
AIFMEDIA || YÒRÙBÁDÙNL'ÉDÈ
0 comments:
Post a Comment