ÈDÈ ÀMÚLÒ MÉJÌLÉLỌ́GBỌ̀N LÁWÙJỌ ÒFIN
(32 VOCABULARY Of LAW)
Ẹ̀sùn/ẹjọ́ - Litigation
Olùpẹ̀jọ́ tàbí Olùjẹ́jọ́ - Litigants
Plaintiff - Olùpẹ̀jọ́
Defendants - Olùjẹ́jọ́
Lawsuit - Ìpẹ̀jọ́
Magistrate Court - Ilé-Ẹjọ́ májísíréètì
Customary Court - Ilé-Ẹjọ́ Ìbílẹ̀
Sharia Court - Ilé-ẹjọ́ Ṣàríà
Appeal Court - Ilé-ẹjọ́ Kò tẹ́milọ́rùn
Tribunal - Ilé-Ẹjọ́ tó ń gbọ́ ẹ̀sùn ìdìbò
High Court - Ilé - ẹjọ́ Gíga
Supreme Court - Ilé-ẹjọ́ tó ga jùlọ.
Magistarte judge - Adájọ́ Ilé-Ẹjọ́ májísíréétì
Chief judge - Adájọ́ Àgbà
Attorney General - Amòfin Àgbà
Counsel - Àwọn Amòfin/Agbẹjẹ́rọ̀
Lawyer - Agbẹjórò
Senior Advocate of Nigeria (SAN) - Oyè Agbẹjọ́rò Àgbà Ilẹ̀ Nàìjíríà
Evidence - Ẹ̀rí
Exhibit - Ẹrú òfin
Witness - Ẹlẹ́rìí
Surety - Onídùúró
Charge - Gbígbé ra ẹni re Ilé Ẹjọ́
Fine - Owó Ìtanràn
Punishmnt - Ìjìyà
Oath - Ìbúra
Jurisdiction - Ẹnu ààlà ìgbẹ́jọ́
Capital Punishment - Ìjìyà ńlá
Disharge - Ìdásílẹ̀
Acquital - Ìdàsílẹ̀ l'áàfíà
Murder case - Ẹjọ́ apànìyàn
Bail - Gbígbà onídùúró
Preserving Yorùbá godly heritage is our concern.
AIFMEDIA || Yorùbá Dùn lÉdè
0 comments:
Post a Comment