Ìtàndòwe - Ẹnití kò le se bí aláàárù l'Óyìngbò, kò le se bí Adégbọrọ̀ l'Ọ́jà ọba
Ìtàndòwe - Ẹnití kò le se bí aláàárù l'Óyìngbò, kò le se bí Adégbọrọ̀ l'Ọ́jà ọba Adégbọrọ̀ fi ìlú Ìbàdàn sílẹ̀, ó kọ rí sí ìlú Èkó láti lọ ṣe iṣẹ́ alábàárù ní agbègbè kan tí[....]